Tolulope Emmanuel, Osogbo
Awon omo ile igbimo asofin ipinle Osun ti ni kawon olopa loo fi pampe oba gbe komisanna tele foro ile ati aato ilu nipinle Osun, Onorebu Muyiwa Ige bayii.
Igbese la gbo pe ko seyin bi won se ni okunrin omobibi Oloogbe Bola Ige yii se kuna lati je ipe awon omo ile igbimo asofin lati waa so tenu e lori ipa to ko ninuu pipin ile ijoba to wa nilu Ilobu.
A gbo pe olori awon omo ile to poju nile asofin, Onorebu Timothy Owoeye lo buwo lu iwe pe kawon olopa loo di Muyiwa Ige ni papamora wa sile asofin.
Nigba tawon oniroyin kan si Ige, o ni oro naa ya oun lenu nitori ko si enikeni to fun oun ni leta pe awon omo ile igbimo asofin fee ri oun rara.
O ni oun ko mo idi tawon asofin fi gbe igbese naa si oun.
Wednesday, 13 December 2017
Home
/
iroyin
/
iroyin-agbegbe
/
iroyin-oselu
/
Adiye ti n jefun araa won o! Awon omo Aregbesola fee fi pampe ofin gbe Muyiwa, omo Bola Ige
Adiye ti n jefun araa won o! Awon omo Aregbesola fee fi pampe ofin gbe Muyiwa, omo Bola Ige
Tags
# iroyin
# iroyin-agbegbe
.Njeetigbo
.
iroyin-oselu
Labels:
iroyin,
iroyin-agbegbe,
iroyin-oselu
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment