Tolulope Emmanuel, Osogbo
Witiwiti lawon eeyan ilu Ejigbo bo moto abenugan ile igbimo asofin ipinle Osun, Onorebu Najeem Salam lasiko to n pin nnkan to mu bo lati ilu oyinbo to lo fun won.
Lara awon nnkan ti abenugan ohun, to tun je okan lara awon to n gbero lati dije funpo gomina Osun lodun 2018 ha fun won ni Tii-Olokun, Gala ati suuti tom-tom.
Bo tile je pe oju otooto lawon araalu fi wo igbese naa, sibe awon ti won gba lara e so pe owo awon naa lo n na, o si di dandan kawon gba nibe.
No comments:
Post a Comment