IROYIN YAJOYAJO

Friday, 27 June 2025

Erin wo! Alawo ti ilu Ilawo, Ọba Oyewọle, ti waja


Alawo ti ilu Ilawo nijọba ibilẹ Ejigbo nipinlẹ Ọṣun, Ọba Abdulazeez Ọladepo Oyewọle 111, ti darapọ mọ awọn babanla rẹ.


Ọdun 2016 ni gomina ijẹta l'Ọṣun, Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla, gbe Ọba Oyewọle ga di igbakeji ninu ipo lọbalọba.


No comments:

Post a Comment