IROYIN YAJOYAJO

Saturday, 5 July 2025

Adajọ ju ọrẹ Apetumodu sẹwọn oṣu mẹtadinlọgbọn, wọn kede ọjọ idajọ Ọba Oloyede


Adajọ United States District Court ti ran Pasitọ Edward Oluwasanmi ti wọn jọ fi ẹsun kiko owo COVID-19 jẹ kan si ẹwọn oṣu mẹtadinlọgbọn.

Ni ti Apetu ti ilu Apetumodu nipinlẹ Ọṣun, lẹyin to ti sọ nile ẹjọ pe ki ijọba orileede Amẹrika gbẹsẹ le gbogbo dukia oun lorileede naa, ile ẹjọ sọ pe yoo gba idajọ tiẹ lọjọ kinni oṣu kẹjọ ọdun yii.

No comments:

Post a Comment