IROYIN YAJOYAJO

Sunday, 13 July 2025

Ah! Awujalẹ ilẹ Ijẹbu, Ọba Adetọna, ti waja!


Ọba Sikiru Adetọna, Awujalẹ ilẹ Ijẹbu nipinlẹ Ogun la gbọ pe o ti darapọ mọ awọn babanla rẹ.


Ọjọ Aiku, Sannde, ọjọ kẹtala oṣu keje ọdun yii la gbọ pe baba ẹni ọdun mọkanlelaadọrun ọhun waja.

No comments:

Post a Comment