Aarẹ orileede yii ana, Muhammadu Buhari ni wọn ti kede pe o ti ku siluu London bayii.Ọkan lara awọn abẹsinkawọ rẹ, Bashir Ahmad lo fi ikede naa sori ikanni Tuita rẹ.
No comments:
Post a Comment