Elekusa ti ilu Ekusa nijọba ibilẹ Odo Ọtin nipinlẹ Ọṣun, Ọba John Ọmọtọṣọ Makanjuọla Oyelusi Kẹta, ti darapọ mọ awọn babanla rẹ.
Gẹgẹ bi atẹjade ti ọkan lara awọn ọmọ baba, Ọmọọba Adekunle Makanjuọla, fi sita, ọjọ kọkandinlọgbọn oṣu kẹfa ọdun yii ni Ọba Oyelusi rewalẹ asa.
O ni laipẹ lawọn mọlẹbi ati ilu lapapọ yoo kede bi eto isinku ọba naa yoo ṣe lọ.
No comments:
Post a Comment