IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 23 July 2025

Lobatan! Sanya Omirin ti kọwe fi ẹgbẹ oṣelu PDP silẹ


Aṣofin to n ṣoju awọn eeyan Guusu Ijeṣa nile igbimọ aṣofin apapọ orileede yii, Hon. Omirin Emmanuel Olusanya, ti kọwe fi ègbẹ oṣelu PDP silẹ.

Ninu léta to kọ si alaga wọọdu rẹ nijọba ibilẹ Ila-Oorun Atakunmọsa ni Iperindo lọjọ kẹtadinlogun oṣu keje ọdun yii lo ti sọ pe ija ojoojumọ ti ko lojutu lo fa a ti oun fi kuro nibẹ.

No comments:

Post a Comment