IROYIN YAJOYAJO

Friday, 15 August 2025

Oṣere tiata nni, Oloye Kanran, ti ku o


Ọkan pataki lara awọn oṣere tiata ilẹ wa nni, Ṣẹgun Rẹmi, ti gbogbo aye mọ si Chief Kanran, ti jade laye.


Aarọ ọjọ Fraide ọsẹ yii ni ọkunrin naa jade laye lẹyin to lo ọdun mejilelaadọrin laye.


Ọmọbibi Keesi nipinlẹ Ogun ni Kanran. O dari ọpọlọpọ fiimu nigba aye rẹ.


Lara awọn fiimu to ti kopa ni Vigilante, Idunnu, Orire, Ọfa Oro, Ajaka Oko, Ọba Okuaye, Ile le ati bẹẹ bẹẹ lọ.

No comments:

Post a Comment