IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 31 October 2024

O ma ṣe o! Oloye Abiọla Morakinyọ ti jade laye


Kọmiṣanna fun eto iṣuna nigba aye ipinlẹ Ọyọ ọjọsi, Oloye Abiọla Morakinyọ ti jade laye. 


Ọjọ Wẹsidee, ọgbọnjọ oṣu kẹwaa ọdun yii la gbọ pe baba naa rewalẹ aṣa. 


Ọmọbibi ilu Gbọngan nipinlẹ Ọṣun ni, o si jẹ ọkan pataki lara awọn aṣaaju ẹgbẹ oṣelu PDP.

No comments:

Post a Comment