IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 22 April 2026

Minisita fun ọrọ ina ijọba, Adebayọ Adelabu, ti kọwe fipo silẹ


Oloye Adebayọ Adelabu to jẹ minisita fun ọrọ ina ijọba lorileede Naijiria ti kọwe fipo silẹ bayii.


Ninu lẹta kan to fi ṣọwọ si Aarẹ Tinubu nipasẹ akọwe funjọba apapọ lo ti sọ pe ọgbọnjọ oṣu kẹrin ọdun yii loun yoo fiṣẹ silẹ.


O ni igbesẹ naa ko ṣẹyin ipinnu oun lati dupo gomina ipinlẹ Ọyọ eleyii ti oun ti ni lọkan lati ọdun 2016.


Lẹta ọhun niyii:

No comments:

Post a Comment