IROYIN YAJOYAJO

Tuesday, 29 October 2024

Lobatan! Ẹgbẹ APC Ọṣun ni ki Arẹgbẹṣọla lọọ rọọkun nile


Ẹgbẹ osẹlu All Progressives Congress (APC) nipinlẹ Ọṣun ti sọ pe ki gomina ana l'Ọṣun, Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla, lọọ rọọkun nile. 


Igbesẹ naa ko ṣẹyin ẹsun oniruuru ti wọn fi kan Arẹgbẹṣọla ninu eyi ti wọn ti ni o pin ẹgbẹ si meji l'Ọṣun. 


Wọn ni yoo rọọkun nile titi digba ti abajade igbimọ kan ti wọn gbe kalẹ lati ṣewadii ẹnikẹni to ba ṣe nnkan to lodi si ẹgbẹ. 


Ẹkunrẹrẹ nbọ laipẹ....

No comments:

Post a Comment