Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu ti fi oniruuru ami-ẹyẹ da awọn ọmọ Naijiria ti wọn ko ipa manigbagbe ninu ọrọ ijọba tiwantiwa lọla.
Bi aarẹ ṣe kede orukọ awọn to wa laye fun ami ẹyẹ yii, naa lo kede fun awọn to ti doloogbe.
Lasiko ipade to ṣe pẹlu apapọ awọn ọmọ ile igbimọ aṣofin agba atawọn ọmọ ile igbimọ aṣofin apapọ layajọ ọjọọ June 12 ti ọdun yii lo kede wọn.
Atupalẹ orukọ wọn niyii:
1. Prof. Wole Soyinka (GCON)
2. Prof. Olatunji Dare (CON)
3. Kunle Ajibade (OON)
4. Nosa Igiebor (OON)
5. Dapo Olorunyomi (OON)
6. Bayo Onanuga (CON)
7. Ayo Obe (OON)
8. Dare Babarinsa (CON)
9. Bishop Matthew Hassan Kukah (CON)
10. Senator Shehu Sani (CON)
11. Governor Uba Sani (CON)
12. Barrister Femi Falana, SAN (CON)
13. Prof. Shafideen Amuwo (CON)
14. Barrister Luke Aghanenu (OON)
15. Senator Tokunbo Afikuyomi (CON)
16. Hon. Labaran Maku (OON)
17. Dr. Tunji Alausa (CON)
18. Mr Nick Dazang (OON)
19. Hon Abdul Oroh (OON)
20. Odia Ofeimun (CON)
21. Seye Kehinde (OON)
22. Barrister Felix Morka (CON)
23. Barrister Ledum Mitee (CON)
24. Hon. Olawale Osun (CON)
25. Dr. Amos Akingba (CON)
26. Prof. Segun Gbadegesin (CON)
27. Mobolaji Akinyemi (CFR)
28. Dr. Kayode Shonoiki (CON)
29. Prof. Julius Ihonvbere (CON)
30. Prof. Bayo Williams (CON)
31. Sen. Abu Ibrahim (CFR)
32. Sen. Ame Ebute (CFR)
33. Uncle Sam Amuka Pemu
34. Ken Saro Wiwa (CON)
35. Saturday Dobee (OON)
36. Nordu Eawo (OON)
37. Daniel Gbooko (OON)
38. Paul Levera (OON)
39. Felix Nuate (OON)
40. Baribor Bera (OON)
41. Barinem Kiobel (OON)
42. John Kpuine (OON)
Posthumous National Honours
1. Shehu Musa Yar’Adua (GCFR)
2. Prof. Humphrey Nwosu (CON)
3. Rear Admiral Ndubuisi Kanu (CON)
4. Alhaji Balarabe Musa (CFR)
5. Pa. Alfred Rewani (CFR)
6. Bagauda Kaltho (OON)
7. Chima Ubani (OON)
8. Dr. Beko Ransome-Kuti (CON)
9. Alao Aka Bashorun (CON)
10. Chief Frank Kokori (CON)
11. Emma Ezeazu (OON)
12. Bamidele Aturu (OON)
13. Fredrick Fasehun (CON)
14. Professor Festus Iyayi (CON)
15. Dr John Yima Sen (OON)
16. Alhaja Sawaba Gambo (CON)
17. Dr. Edwin Madunagu (CON)
18. Dr. Alex Ibru (CON)
19. Chief Bola Ige (CFR)
20. Pa. Reuben Fasoranti (CFR)
21. Sen. Ayo Fasanmi (CON)
22. Sen. Polycarp Nwite (CON)
23. Dr. Nurudeen Olowopopo (CON)
Bakan naa ni aarẹ kede pe oun fun Ken Sarowiwa ni idarijin patapata.
No comments:
Post a Comment