Oluọmọ Gbenga Owolabi to jẹ alaga ijọba ibilẹ Ariwa Ifẹ nigba kan ri ti jade laye.Laarọ oni Sannde ni wọn kede iku ọkunrin oloṣẹlu ọmọbibi ilu Ifẹ naa.Ẹkunrẹrẹ nipa iku rẹ nbọ laipẹ...
No comments:
Post a Comment