Inu ibẹrubojo lawọn eeyan agbegbe Ikoyi-Ile nijọba ibilẹ Oriire nipinlẹ Ọyọ wa bayii latari lẹta kan ti wọn ri nibẹ.
Lẹta ọhun, ti ko ni deeti, la gbọ pe wọn ba niwaju ati lẹyinkule ile kan niluu naa.
Gẹgẹ bo ṣe wa ninu lẹta ọhun ti akọle rẹ jẹ 'Lati Ọdọ Bandit', awọn ti wọn kọ lẹta naa sọ pe awọn yoo ṣabẹwo ibanujẹ si agbegbe naa logunjọ oṣu ti a wa yii.
Lẹta naa niyii:


No comments:
Post a Comment