IROYIN YAJOYAJO

Sunday, 1 March 2026

O ma ṣe o! Ọkan lara awọn ibeji olorin ẹmi nni, Adegbodu Twins, ti jade laye


Taiwo Adegbodu, ọkan lara awon ibeji akọrin ẹmi ti wọn n jẹ Adegbodu Twins JP ti jade laye.


Ninu ọrọ ti ekeji rẹ fi sori feesibuuku nidaji ọjọ Sannde, ọjọ Kinni oṣu Kẹta ọdun yii lo ti ni iku naa nira fun oun lati gba.


Ọrọ ọhun niyii: 




Ọmọbibi ilu Saki nipinlẹ Ọyọ ni awọn ibeji yii.


Ẹkunrẹrẹ nbọ laipẹ...

No comments:

Post a Comment