Gomina Ademọla Adeleke ti rọ Apetumodu ti ilu Ipetumodu, Ọba Joseph Oloyede, loye.
Oni, ọjọ Aje, ọjọ Kọkanla, oṣu Karun nijọba gbe igbesẹ naa.
Atẹjade latọwọ agbẹnusọ fun gomina, Ọlawale Rasheed, sọ pe eyi ko sẹyin bi ijọba ṣe ti tẹwọ gba ojulowo akọsilẹ ti wọn fi ran Ọba Joseph lẹwọn lorileede Amẹrika.

No comments:
Post a Comment