Ọkan lara awọn to kọ iwe ofin orileede Naijiria lọdun 1976, Dokita Samuel Oluṣẹgun Ọṣọba, ti jade laye.Ninu ile rẹ niluu Ijẹbu-Ode la gbọ pe o ku si nirọlẹ oni Tọsidee.Ẹni ọdun mejilelaadọrun-un ni baba onkọtan naa k'Ọlọjọ to de.
No comments:
Post a Comment