IROYIN YAJOYAJO

Friday, 10 July 2026

Ṣe ẹ ti gbọ nnkan to ṣẹlẹ si awọn olukọọ ati akẹkọọ Oriire nipinlẹ Ọyọ ti wọn ji gbe?


Iroyin to n tẹ wa lọwọ bayii ti fidi rẹ mulẹ pe awọn akẹkọọ ati olukọ ijọba ibilẹ Oriire nipinlẹ Ọyọ tawọn agbebọn ji gbe ti gba itusilẹ.


Ọjọ kẹẹdogun oṣu karun ọdun yii lawọn agbebọn ya wọ ileewe mẹta nijọba ibilẹ naa, ti wọn si ko akẹkọọ mọkandinlogoji ati olukọ meje.


Amọ ṣa, laipẹ yii ni oludamọran pataki fun Aarẹ Tinubu, Bayọ Ọnanuga, fi si ori itakun tuita rẹ pe awọn ẹṣọ alaabo ti gba awọn eeyan wọnyii silẹ lọwọ awọn to ji wọn gbe


Ẹkunrẹrẹ nbọ laipẹ...

No comments:

Post a Comment