O ma ṣe o! Awọn janduku ṣeku pa Amọtẹkun kan l'Ọṣun Njeetigbo 11:07Awọn janduku agbebọn ti ran ọkan lara awọn ọmọ ajọ Amọtẹkun nipinlẹ Ọṣun, Lamidi Abiọdun, si ọrun ọsan gangan lọjọọ Wẹsidee ọgbọnjọ oṣu kẹri... Kaa Siwaju
Laarin oṣu meji, ijọba ibilẹ Irewọle nipinlẹ Ọṣun padanu alaga meji Njeetigbo 16:24Alaga ijọba ibilẹ Irewọle nigba kan ri, Honourable Gbadebọ Oyejide, ti jade laye. Oyejide tun ti figba kan ri wa nile igbimọ aṣofin ipinlẹ ... Kaa Siwaju
Wolii Olu Alọ taṣiri ohun to n fa wahala aisi aabo to peye lorileede Naijiria Njeetigbo 20:16Pẹlu bi wahala iṣekupani ṣe n fojoojumọ gbilẹ sii, paapaa ni apa Guusu orileede yii, Wolii Sam Olu Alọ ti ke si ijọba apapọ lati ra oniruur... Kaa Siwaju
Ẹ dakẹ Rumọs, Gomina Adeleke ko le kuro ninu ẹgbẹ PDP lailai - Igbimọ alaṣẹ ijọba Ọṣun Njeetigbo 13:25Awọn ọmọ igbimọ alaṣẹ ipinlẹ Ọṣun ti sọ pe irọ to jinna sootọ ni ahesọ kan to n lọ kaakiri bayii pe o ṣee ṣe ki Gomina Ademọla Adeleke maa ṣ... Kaa Siwaju
Ọna ti n la, o si ti han pe a maa gba ipinlẹ Ọṣun lọdun 2026 - Igbimọ Agba Ọṣun Njeetigbo 08:08Igbimọ Agba Ọṣun ninu ẹgbẹ All Progressives Congress, labẹ alaga wọn, Ẹnjinia Ṣọla Akinwumi, ti sọ pe gbogbo nnkan to n ṣẹlẹ bayii ti fi han... Kaa Siwaju
Ibalopọ: Ọpọlọpọ ẹtọ lawọn obinrin ni labẹ ofin, ṣugbọn ti wọn ko mọ - OYAWIN Njeetigbo 19:19Ajọ kan ti ko rọgbọku lejọba, Ọlabọde Youth and Women Initiatives (OYAWIN) pẹlu ibaṣepọ AmplifyChange Pamoja Project, ti ṣedanilẹkọ ọlọjọ me... Kaa Siwaju
Fungba keji, awọn janduku dana sun ile-ẹjọ giga ipinlẹ Ọṣun, lawọn araalu ba ni ọrọ naa mu ifura lọwọ Njeetigbo 16:17Ọjọ kẹtala oṣu keji ọdun 2017 lawọn janduku kan ti kọkọ lọ dana sun ile ẹjọ giga ijọba ipinlẹ Ọṣun to wa niluu Ileṣa, iyẹn Court 2, ti ijọba... Kaa Siwaju
Poopu Ijọ Aguda ti ku o! Njeetigbo 10:16Poopu ijọ Aguda, to tun jẹ Bisọọpu ilẹ Roomu, Pope Francis, ti jade laye. Ẹni ọdun mejidinlaadọrun ni ojiṣẹ Ọlọrun naa ki iku to pa oju rẹ d... Kaa Siwaju
Lẹyin ti John sa kuro lakolo ọlọpaa, lo tun lọọ jale, lawọn Amọtẹkun ba mu un Njeetigbo 18:18John Uba, ọmọ ọdun mẹrindinlọgbọn ni ọwọ awọn ajọ Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun ti tẹ bayii lori ẹsun ole jija. Gbagedeọrọ gbọ pe akolo awọn ọlọpaa t... Kaa Siwaju
Owo isọmọlorukọ ni mo n wa ti mo fi lọọ jale - Saheed jẹwọ l'Oṣogbo Njeetigbo 15:14Ọmọbibi agboole Balogun-bii-irọ niluu Oṣogbo ni Saheed Babatunde ẹni ọdun mẹrindinlọgbọn ti ọwọ ajọ Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun tẹ laipẹ yii lori ẹ... Kaa Siwaju
Famurewa ṣedaro Adeniji, o ni onirẹlẹ ati aṣiwaju to ṣe e fọkan tan ni Njeetigbo 16:57Ẹnjinia Israel Ajibọla Famurewa to ti figba kan ri ṣoju awọn eeyan Ila Oorun Ọṣun nile igbimọ aṣofin apapọ, ti sọ pe ibanujẹ nla ni iku alak... Kaa Siwaju
Iyansipo: Igbimọ Agba Ọṣun ba alaga ẹgbẹ APC dawọọdunnu Njeetigbo 06:58Lorukọ awọn Igbimọ Agba ninu ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) nipinlẹ Ọṣun, alaga wọn, Ẹnjinia Ṣọla Akinwumi, ti fi idunnu wọn han... Kaa Siwaju
Igbimọ Agba Ọṣun ṣedaro iku Dokita Rauf Adeniji 'Kongo' Njeetigbo 11:00Alaga Igbimọ Agba ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress nipinlẹ Ọṣun, Ẹnjinia Sọla Akinwumi, ti ṣapejuwe iku alakoso fun eto gbogbo ninu ẹgbẹ... Kaa Siwaju
Lẹyin ọjọ mẹta to kuro lọgba awọn ajinigbe, oloye ẹgbẹ APC, Adekunle Adeniji, jade laye Njeetigbo 14:42Ọmọbibi ilu Ileefẹ nni, to tun jẹ alakoso eto gbogbo ninu ẹgbẹ oṣelu APC lorileede yii, Hon. Abdul-Raif Adekunle Adeniji, ti jade laye. Ọjọ ... Kaa Siwaju
Njẹ ẹ ti gbọ? Awọn ara Osun West fontẹ lu Gomina Adeleke fun saa keji, wọn ni ko sẹni to tun le ṣe bii tiẹ Njeetigbo 16:41Bi idibo gomina ṣe n kanlẹkun nipinlẹ Ọṣun, awọn eeyan agbegbe Iwọ-Oorun Ọṣun ti sọ pe Gomina Ademọla Adeleke yoo lọ fun saa keji rẹ lọdun 2... Kaa Siwaju